Èdè Yorùbá Rẹwà

Translator
4.6 star rating
38

About Èdè Yorùbá Rẹwà

A dá ojú ìwé yí sílè fún àwọn ènìyàn tí wọn fẹ́ràn láti mò nípa èdè Yorùbá, àṣà àti ìṣe ilẹ̀ kóòtù ojire. Kíkó àwọn ọmọ wa ni Èdè Yorùbá

Reviews

User

Àsìkò ìdá ara wa l'ẹ̀kọ́ #EdeYorubaRewa

User

Ǹjẹ́ ẹ mọ àwọn olórí Nàìjíríà dada? Tani ó wà nínú àwòrán yìí? #EdeYorubaRewa

User

Àsìkò ìdá ara wa l'ẹ̀kọ́ #EdeYorubaRewa

User

Ǹjẹ́ ẹ mọ ẹni tí ó wà nínú àwòrán yìí? #EdeYorubaRewa

User

Ìbéèrè ńlá. #EdeYorubaRewa

User

Ẹ parí òwe yìí. #EdeYorubaRewa

User

A tún ti pàdánù ọ̀kan nínú ònkọ̀wé pàtàkì pẹ̀lú èdè Yorùbá.
Olóògbé Ọládẹ̀jọ Òkédìjí ni ó dágbére fáyé ni ẹni ọdún mọkandiladorun (89 years). Ọlọhun báwa delè fún wọn, ko ró àwọn ẹbí lójú. #EdeYorubaRewa

User

Nígbà tí mo wà ní ilé ìwé girama Ọlọhun ooooo mo ma fi roba yìí ṣeré oooo.
Ǹjẹ́ ìwọ fi ṣeré.?
#EdeYorubaRewa

User

Beeni àbí bẹẹkọ? #EdeYorubaRewa

User

Àyẹ̀wò ojú. Ẹ ko nọ́mbà tí ẹ rí. #EdeYorubaRewa

User

Ọ̀RỌ̀ ìṣítí #EdeYorubaRewa

User

#ÈdèYorùbáRewà

User

Àsìkò ìdá ara wa l'ẹ̀kọ́. #ÈdèYorùbáRewà

User

Alo ooo Àlọ́ ọ̀ọ̀ọ̀ Àlọ́ yìí dá lórí ọmọdé kan àti bàntẹ́...
Ni ayé àtijọ́, nígbà tí ojú ń bẹ ní ọ̀rúndún, tí ẹranko ń fọhùn bí ènìyàn, ọmọdékùnrin kan wà ní ìlú kan. Ọmọdé yìí máa ń tẹ́lẹ̀ àwọn òbí rẹ̀ lọ sí oko. Bàbá ọmọdé yìí ní bàntẹ́ kan, bàntẹ́ jẹ́ aṣọ kékeré tí àwọn àgbàlagbà máa ń wọ̀ sí abẹ́ aṣọ. A lè fi bàntẹ́ wé pátá àwọ̀tẹ́lẹ̀ òde òní. Gbogbo ìgbà ni ọmọdé yìí máa ń tọju ìbàntẹ́ bàbá rẹ̀ nípa fífọ̀ àti kíká wá sí ilé.
... Ní ọjọ́ kan, ọmọdé yìí gbàgbé bàntẹ́ sí oko, ó dé ilé tán kí ó tó rántí pé òun kò mú bàntẹ́ wá sí ilé, ṣùgbọ́n kìn ni ó bá pàdé lóko? Bí ọmọdé yìí ṣe ní kí òun náwo mú bàntẹ́ ni ó gbọ́ tí bàntẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí kọrin báyìí pé:
Bàntẹ́_____ Ọmọ gbàgbé mi sóko Ègbè______ Bàntẹ́ Bàntẹ́_____ Ó tún padà wá múni Ègbè______ Bàntẹ́ Bàntẹ́_____ Ó di gbì okú lọ Ègbè______ Bàntẹ́ Bàntẹ́_____Ó di gbì ikú dé Ègbè______Bàntẹ́.
Bí bàntẹ́ tí dáké orin, ni ọmọdé yìí fò sánlẹ̀ ó sì kú.
Nígbà tí àwọn òbí ọmọ yìí retí rè tí wọn kò ríi ni àwọn náà bá gbéra ó di oko. Nígbà tí wọ́n dé oko, wọ́n rí òkú ọmọ wọn nílè àti bàntẹ́ tí ọmọ padà wá mú lóko. Bí àwọn òbí ọmọ yìí ti gbée nílè tí wọ́n sì tún nawọ́ láti mú bàntẹ́, ìyàlẹ́nu ni ó jé fún wọn pé orin ni bàntẹ́ fi dá wọn lóhùn bíi ti àkókò. Bí bàntẹ́ tí parí orin rè ni àwọn òbí ọmọdé yìí náà fò sánlẹ̀ tí wọ́n kú. Lẹ́hìn èyí ni àwọn aládùúgbò náà wá sí oko ṣùgbọ́n bákan náà ni. Ìròyìn wá kàn dé ọ̀dọ̀ ọba ìlú. Ọba pàṣẹ pé kí ọ̀sanyìn ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́wàá ó lọ mú bàntẹ́. Ọ̀sanyìn ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́wàá náà lọ ṣùgbọ́n òun náà kú sí oko. Gbogbo àwọn ọ̀sanyìn ọba náà ni wọ́n lọ tí àwọn náà sì kú sí oko.
Nígbà tí ó pẹ́,ọ̀sanyìn ẹlẹ́sẹ̀ kan yọjú síta, ó sọ pé òun yóò mú bàntẹ́ wá sí ilé. Gbogbo ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí fi ṣe yẹ̀yẹ́ pé ohun tí ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́wàá kò rí mú wálé ni ẹlẹ́sẹ̀ kan fẹ́ dánwò. Wọ́n tún sọ pé "ibi tí èfúùfù ti ń gbé kẹ̀tẹ̀pẹ̀ Ogi tí èlùbọ́ ni òun yóò ṣe ọmọ ìta". Ọba sọ fún àwọn ènìyàn kí wọ́n fi Ọ̀sanyìn ẹlẹ́sẹ̀ kan sílè kí ó gbìyànjú kí ó pa itú ọwọ́ rẹ. Ọ̀sanyìn ẹlẹ́sẹ̀ kan lọ sí oko, ó pa itú ọwọ́ rè ó sì mú bàntẹ́ wá sí ilé.
Ìtàn yìí kó wa wípé kò yẹ kí á máa f'ojú tẹ́ńbẹ́lú ẹnikẹ́ni nítorí ẹ̀dá kò láròpin..
Mo lérò wípé ẹ gbádùn Àlọ́ yìí. Ẹsẹ́ púpọ̀.
#EdeYorubaRewa
See More

User

Let us all learn to be patient. #EdeYorubaRewa

User

Not matter how long you cover lie, the true will definitely prevail....

User

Ọ̀RỌ̀ ìṣítí #EdeYorubaRewa

User

Òwe Yorùbá 9 #EdeYorubaRewa

User

Òwe Yorùbá 7 #EdeYorubaRewa

User

Édé yorubà dàrà lø pó lo po, o dun gbó ósí dun kà mo ni ífé pupó ní to rí omo yorúbà ní mo jééé

User

Èdè Yorùbá da pupo

User

proudly fun! !! OMO YORUBA!!!!!!am very grateful to Almighty God to be a YORUBA

User

Yoruba is an Interesting language which everybody loves to speak or hear

User

Very good to me osi dara fun gbogbo omo kaaro ojiire lati maaka.

User

This program is excellent, it make some of our people that has lost the value to pick up.

User

It's an educative and exciting group anyone would wanna be...I love it

User

It my culture and I love it so much, because ede wa asa wa ni ko sii ohun tio dun to.

User

Intact it was highly and extremely interesting I love it so much

User

Ikan gboogi laarin gbogbo awon to wa,hmm bee na lorewa to

User

I luv dis page I wish to join d group Ede Yoruba Rewa gan nii

User

Great page, making sure that the root and legacies of the Yoruba people are not forgotten

User

Great concept. Got glued to the page. Thumbs up!

User

So impressive, we should all let our children No how our language & culture is very important , Ki Olorun ko ran lowo o.

User

J'ai aimé par ce que c'est m'a langue et j'aime bien ma culture

User

I love the page most especially they encourage us to respect and not to forget ours source

User

I love Yoruba nd i love there proverb ...though am not a Yoruba girl

User

EJe kagbe Ede Yoruba Laruge bcs l am proud too be a Yoruba

User

Ni inu Oyo baba kan wa li agbole arikusa oruko baba naa je odediran on I iyawo kan soso iyawo naa wa ni inu oyun sungbo ko ri omo bi asake ni oruko iyawo re won GBE asake losi odo iya osun iya osun sofun arikusa wipe to a fekin asake korin omo bi kolosi inu Igbo kosewo koloja ewe abiye wa fun ohun kosi gbodo ju wakati kan lo inu Igbo naa Igbo naa sini agbara pupo kosi eniti olewo inu Igbo naa ti ko ni kusi oju onaa ni biti arikusa tilo opade iya agba kan iya agba naa so fun wipe ki arikusa kopada so ile iya naa so fun wipe konibo eruba arikusa o rowipe se ki ohun pada ni abiki ohun malo ipada di oju keji

More about Èdè Yorùbá Rẹwà

+2347030009750
https://edeyorubarewa.com